Yoruba gege bi ede akokunteni

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Of in eto eko ede abinibi lo fa eko ede Akokunteni. Ede akokunteni ni ki a ko ede miiran ti ki i se ti awujo ti a bi ni si kun eyi ti a mo teletele. Eyi ni pe ki a ko ede ti a ko gbo teletele ri mo ti abinibi eni. Awon wo ni o le je akekoo? Ko si eni ti ko le ko ede kun tire. Omode n ko o, agba n koo. Bi apeere agbalagba ti o je omo ile Hausa ti ise gbe lo si ilu Ibadan le pinnu lati ko ede Yoruba. Eyi yoo je ki o rorun fun un lati ba awon alajogbe re soro laisi inu fuu edo fuu. Ajumose yoo waye laarin re ati awon ore tuntun to sese ni.