Ápártáìdì
Ápártáìdì (Geesi: /əˈpɑːrteɪd/; Àdàkọ:IPA-af, segregation; lit. "aparthood") ni sistemu ijoba ìṣègbéraga àwọn òyìnbó to da lori iyasotooto eya ti awon oyinbo fi tipatipa fi sejoba ni orile-ede Guusu Afrika ati South West Africa (ti a mo si Namibia loni) lati odun 1948 titi di 1994[note 1] Apartaidi je ijoba tipatipa to da lori baasskap (tabi Ìṣègbéraga àwọn òyìnbó), to mu daju pe awon oyinbo, botile je pe iye won ko po, gaba le ori gbogbo eniyan ni orile-ede Guusu Afrika ninu oselu, awujo ati okowo.[4] Gegebi sistemu awon oyinbo yi se to, awon oyinbo ni won gbudo siwaju ni gbogbo igba, awon omo ara Asia te le won, be sini awon alawodudu ara Afrika lo gbodo gbeyin.[4] The economic legacy and social effects of apartheid continue to the present day.[5][6][7]
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Repeal of Population Registration Act". C-Span. 17 June 1991. Retrieved 7 June 2018.
- ↑ Myre, Greg (18 June 1991). "South Africa ends racial classifications". Associated Press (Cape Girardeau: Southeast Missourian). https://news.google.com/newspapers?nid=1893&dat=19910618&id=3sQfAAAAIBAJ&sjid=ltgEAAAAIBAJ&pg=5582,6356040. Retrieved 1 March 2018.
- ↑ Bartusis, Mark (2012). Gomez, Edmund; Premdas, Ralph. eds. Affirmative Action, Ethnicity and Conflict. New York: Routledge Books. pp. 126–132. ISBN 978-0415627689.
- ↑ 4.0 4.1 Mayne, Alan (1999). From Politics Past to Politics Future: An Integrated Analysis of Current and Emergent Paradigms. Westport, Connecticut: Praeger. p. 52. ISBN 978-0-275-96151-0.
- ↑ Leander (15 June 2015). "Despite the 1994 political victory against apartheid, its economic legacy persists by Haydn Cornish-Jenkins" (in en). South African History Online. http://www.sahistory.org.za/article/despite-1994-political-victory-against-apartheid-its-economic-legacy-persists-haydn-cornish-.
- ↑ "'Apartheid legacy haunts SA economy' - SABC News - Breaking news, special reports, world, business, sport coverage of all South African current events. Africa's news leader.". www.sabcnews.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2 May 2018.
- ↑ "Ramaphosa's tough job on fixing Apartheid legacy". 6 April 2018.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/>
tag was found