Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé-Plateau
Ìrísí
Ipinle Benue-Plateau je ipinle tele ni Naijiria. O je dida ni 27 May 1967 lati awon apa Agbegbe Apaariwa o si wa titi di 3 February 1976, nigba ti won pin si ipinle meji - Benue ati Plateau. Ilu Jos lo je oluilu re nigbana.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon Gomina Ipinle Benue-Plateau
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Joseph Gomwalk (28 May 1967 – July 1975)
- Abdullahi Mohammed (July 1975 – March 1976)