Jump to content

Ìṣedọ́gba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìṣirò àkọ́kọ́ pórópóró

Nínú mathimatiiki ìṣedọ́gba jẹ́ ìdọ́gba tó so ọ̀pọ̀iye mímọ̀rí pọ̀ mọ́ ọ̀pọ̀iye àìmọ̀rí tí à únwá. Ojútùú fún ìṣedọ́gba tó ní iye àìmọ̀rí n yíò jẹ́ ọ̀pọ̀ n tó mú kí ìṣedọ́gba náà ó jẹ́ òọ́tọ́.