Ẹ̀wà Àgànyìn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ewa Agoyin
Alternative namesEwa Aganyin
TypeStreet food
CourseSide Dish, Snack
Place of originNigeria
Main ingredientsBlack Eyed Beans, Bell Pepper, Black/Cameroon Pepper, Onion
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Ẹ̀wà Àgànyìn[1] jẹ́ oúnjẹ àdúgbò tí ó wọ́pọ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pàá pàá jùlọ Ìpínlẹ̀ Èkó [2] Wọ́n ma ń sábà se ẹ̀wà yí kí ó rọ̀ tàbí kí ó fọ́ dára dára .[3] wọ́n sábà má ń jẹ́ ẹ̀wà yi pẹ̀lú ata díndín tí wọ́n fepo gbá ,[4] àmọ́, ata náà ń ta gidi. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni wọ́n máa ń ṣe ìkékúrú orúkọ ẹ̀wà náà 'Ẹ̀wà G'. Àwọn ńkan mìíràn tí wọ́n ma ń fi pèsè ata tàbí ọbẹ̀ rẹ̀ ni epo pupa,Àlùbọ́sà, Edé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Bí wọ́n ṣe ń jẹẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló máa ń fi ẹ̀wà yí jẹ búgan tàbí búrẹ́dì, ti ó sì máa ń jẹ́ kí ó dùn yàtọ̀. Oúnjẹ yí jẹ́ èyí tí ó gbajúmọ̀ láàrín àwọn ènìyàn ilẹ̀ Adúláwọ̀

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ewa Agoyin Recipe". Mamador. Retrieved February 5, 2018. 
  2. Ewa Aganyin: Popularity of street food soaring in Lagos. September 19, 2015. Daily Trust
  3. "23 Nigerian Foods The Whole World Should Know And Love". Buzzfeed.com. June 24, 2015. Retrieved December 21, 2017. 
  4. Seven Popular Bukkas In Lagos. October 2, 2017. The Guardian.