Abubakar Tafawa Balewa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
  1. REDIRECT Àdàkọ:Infobox officeholder

Abubakar Tafawa Balewa (December 1912 – January 15, 1966) je omo orile ede Naijiria, fulani lati apa ariwa ile Naijiria. Balewa je Alakoso Agba (prime minister) akoko fun ile Naijiria ni Igba Oselu Akoko ile Naijiria leyin igba ti Naijiria gba ominira ni odun 1960. Eni ayesi ni kariaye, o gba owo ni orile Afrika gege bi ikan lara awon ti won daba idasile Akojoegbe Okan ara Afrika (Organization of African Unity, OAU).

Igba ewe ati ise-owo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]