Amalia Perez

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Amalia Pérez
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèMexican
Ọjọ́ìbíOṣù Keje 10, 1973 (1973-07-10) (ọmọ ọdún 50)
Mexico City, Mexico
Sport
Orílẹ̀-èdèÀdàkọ:MEX
Erẹ́ìdárayápowerlifting
DisabilityParaplegia
Event(s)44kg - 60kg
Coached byJosé Enrique Alvarado Paiz

Amalia Pérez Vázquez (tí wọ́n bí ní 10 July 1973) jẹ́ ọmọ oeílẹ̀-èdè Mexico eléré-ìdárayá tó máa ń gbé nǹkan tó wuwo, tó wà láàárín 44 kilograms (97 lb) - 60 kilograms (130 lb).[1][2][3] Ó ti jáwé olúborí ní ẹ̀mẹẹrin fún Paralympic champion, òun sì nìkan ni olùgbé nǹkan tó wúwo ní àgbáyé tó gba àmì-ẹ̀yẹ ní ẹ̀ka m ẹ́ta ọ̀tọ̀tọ̀.[4]

Pérez jé ọmọ-ẹgbẹ́ Mexican delegation sí Paralympic Games láti ọdún 2000.[5] Ìkópa rẹ̀ nínú 2000 Summer Paralympics ló mú gba àmì-ẹ̀yẹ onífàdákà rẹ̀ àkọ́kọ́ ní 52 kilograms (115 lb),[6] ó sì tún gba àmì-ẹ̀yẹ onífàdákà mìíràn ní 2004 Summer Paralympics ní Athens, àmọ́ 48 kilograms (106 lb) ni ó gbé ní ayẹyẹ yìí.[7]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Amalia Pérez: mexicana y superpoderosa" (in es). BBC World. 3 September 2012. https://www.bbc.co.uk/mundo/video_fotos/2012/09/120903_video_juegos_paralimpicos_amalia_perez_rg.shtml. Retrieved 30 May 2013. 
  2. Reséndiz, Mac (13 October 2012). "Amalia Pérez: vulnerable y fuerte" (in es). ESPNdeportes. http://espndeportes.espn.go.com/news/story?id=1632866&s=otr&type=story. Retrieved 30 May 2013. 
  3. "Amalia Perez - Para powerlifting | Paralympic Athlete Profile". www.paralympic.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 29 November 2017. 
  4. "¡Récord mundial y tercer oro consecutivo!". sportspedia.com.mx (in Èdè Sípáníìṣì). Sportspedia México. Archived from the original on 2016-09-20. Retrieved 21 September 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named dos2
  6. "Women's Up To 52 kg". paralympic.org (in Èdè Sípáníìṣì). International Paralympic Committee. Archived from the original on 4 March 2016. Retrieved 19 May 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Women's Up To 48 kg". paralympic.org (in Èdè Sípáníìṣì). International Paralympic Committee. Archived from the original on 4 March 2016. Retrieved 19 May 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)