Augustina Ebhomien Sunday

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Augustina Ebhomien Sunday (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún, oṣù kẹjọ, ọdún 1996) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton.[1][2] Ó kọ́ èkọ́ gboyè nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Benson Idahosa University, ní ọdún 2015, ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Summer Universiade, ní ìlú Gwangju, ní orílẹ̀-èdè South Korea.[3]

Àwọn àṣeyọrí rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìdíje ti ilẹ̀ Africa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Venue Partner Opponent Score Result
2019 Alfred Diete-Spiff Centre,

Port Harcourt, Nigeria

Nàìjíríà Peace Orji Nàìjíríà Amin Yop Christopher

Nàìjíríà Chineye Ibere

16–21, 14–21 Bronze Bronze

Ìdíje ti gbogboogbò ti BWF[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàpọ̀ àwọn obìnrin

Year Tournament Partner Opponent Score Result
2014 Uganda International Nàìjíríà Dorcas Ajoke Adesokan Nàìjíríà Tosin Damilola Atolagbe

Nàìjíríà Fatima Azeez

21–14, 9–21, 12–21 Runner-up
2013 Nigeria International Nàìjíríà Deborah Ukeh Nàìjíríà Tosin Damilola Atolagbe

Nàìjíríà Fatima Azeez

21–18, 21–13 Winner

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]