Bim Adewunmi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Bim Adewunmi
Ọjọ́ ìbíLondon, England, United Kingdom
Iṣẹ́Writer, producer, journalist
ÈdèEnglish
Ọmọ orílẹ̀-èdèBritish Nigerian
Notable worksThirst Aid Kit
Years active2014―present

Bim Adewunmi jẹ́ akọ̀ròyìn ilẹ̀ Britain. Òun ni aṣagbátẹrù This American Life ó sì ti fìgbà kan ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí òǹkọ̀wé ní BuzzFeed àti The Guardian. Ó ṣe olóòtú ètò Thirst Aid Kit pẹ̀lú òǹkọ̀wé Nichole Perkins láti ọdún 2017 wọ ọdún 2020. Eré rẹ̀ àkọ́kọ́ ni Hoard, tí wọ́n ṣàfihàn ní tíátà Arcola Theatre, ní oṣù May, ọdún 2019. [1][2][3]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adewunmi bẹ̀rẹ̀ sí ní kọ ìwé lóri èrò àti àṣà ní ọdún 2014, fún The Guardian (Nigeria).[4] Ó di olóòtú fún BuzzFeed ní ọdún 2015.[5] O kúrò ní The Guardian ní oṣù October, ọdún 2018,[4] ó sì darapọ̀ mọ́ ètò orí rédíò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ This American Life tí wọ́n ṣàgbéjáde ní oṣù April, ọdún2019. [6]

Ìgbésí ayé ara ẹni[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìlú Stratford ní apá Ìlà-oòrùn London ni wọ́n bí Adewunmi sí, àwọn òbí rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Yorùbá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó kó lọ sí ìlú London.[7] Ìlú Brooklyn, ní New York ló ń gbé.[8] Ó bí ọmọ kan ní ọdún 2023.[9]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "What does Luminary's very bad week tell us about podcasters' collective power?". Nieman Lab. Retrieved 2019-05-27. 
  2. "Bim Adewunmi recalls the east London that shaped her". Evening Standard (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-05-15. Retrieved 2019-07-15. 
  3. Kang, Inkoo. "Lusting Out Loud". Slate. Retrieved 2019-07-15. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. 4.0 4.1 Adewunmi, Bim (2018-10-20). "Thank you and goodbye, readers: you helped make my dream come true | Bim Adewunmi" (in en-GB). The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/lifeandstyle/2018/oct/20/thank-you-and-goodbye-readers-you-helped-make-my-dream-come-true. 
  5. McAleavy, Emma L. (2018-08-23). "What's on TV Thursday: 'Follow This' on Netflix and the Season Finale of 'American Woman'" (in en-US). The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/2018/08/23/arts/television/whats-on-tv-thursday-follow-this-on-netflix-and-the-season-finale-of-american-woman.html. 
  6. Adewunmi, Bim (2019-04-29). "~some personal news~ today is my first day as a producer with This American Life. So, uh, feel free to hit me up with stories etc. pic.twitter.com/032muBCZS2". @bimadew (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-15. 
  7. "Bim Adewunmi recalls the east London that shaped her". Evening Standard (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-05-15. Retrieved 2019-07-15. 
  8. Twitter (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì) https://twitter.com/bimadew/status/730032917083246593. Retrieved 2020-10-27.  Missing or empty |title= (help)
  9. Adewunmi, Bim (May 14, 2023). "Is the A train as fast as it needs to be?". ...the fuck is this? (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Substack. Retrieved 2023-05-14.