Bimbo Ogunnowo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ogunnowo Taiwo Oladuni jé òṣèrébìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti aṣaralóge.[1] Fíìmù àkọ́kọ́ rè ni Ifejafunmi.[2]

Àtòjọ àwọn fíìmù rè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ifejafunmi
  • Ebute[3]
  • Gucci Girls

Ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2018, òṣèrébìnrin yìí fẹ́ aṣagbátẹrù fíìmù àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan, tí orúkọ rè ń jẹ́ Okiki Afolayan.[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Meet Nollywood's skin-lightening cream merchants". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-12. Retrieved 2022-12-12. 
  2. Online, Tribune (2018-04-24). "10 things you need to know about actress Bimbo Ogunnowo". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-12. 
  3. "Bimbo Ogunnowo". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-12. 
  4. Ekpo, Nathan Nathaniel (2018-10-05). "Actress, Abimbola Ogunnowo in tears of Joy as She Weds lover". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-12-12. 

Àdàkọ:Nigeria-film-actor-stub