Jump to content

Erin-Ijesha Waterfalls

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Erin Ijesha Water fall
Erin-Ijesha Waterfalls lpile ekeji video
Awon Onirinajo ni Olumirin falls ni Erin Ijesha, Osun state

Erin-Ìjẹ̀sà omi-ìṣàn orókè (tí a tún mọ̀ sí omi-ìṣàn orókè Olumirin) wà ní Erin-Ìjẹ̀sà. Ó jẹ́ aṣòùnfà ìrìn-afẹ́ ní ìjọba-ìbílẹ̀ Oríadè, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Nàìjíríà. Ìtàn sọ pé ọ̀kan lára àwọn ọmọ Odùduwà ló ṣe àwárí omi - ìṣàn-orókè yìí ni 1140AD. Wàyí ooo,  gẹ́gẹ́bí "The Nation" ṣe sọ, àwọn ọdẹ ló ṣe àwárí omi ìṣàn orókè Olumirin ni 1140AD. Ìtàn mìíràn sọ obìnrin kan Akinla, olùdásílẹ̀ Ìlú Erin-Ìjẹ̀sà tí ó tún jẹ́ ọmọọmọ Odùduwà ló ṣe àwárí ibùdó ìrìn-afẹ́ yìí lásìkò ìṣípòpadà àwọn aráàlú Ifẹ́ lọ sí Erin-Ìjẹ̀sà.[1] [2]

Ipele méje ni omi-ìṣaǹ-orókè yìí ni, lórí rẹ̀ ni abúlé Abake wà

Omi-ìṣaǹ-orókè Erin-Ìjẹ̀sà yìí jẹ́ ìrìnàjò afẹ́ tó gbajúmọ̀ fún àwọn ilé-ẹ̀kọ́ ní agbègbè náà. Àwọn aráàlú ká omi-ìṣaǹ-orókè yìí gẹ́gẹ́ bíi ààyè abọ̀wọ̀ àti ọ̀nà ìṣàfọ̀mọ́ ẹ̀mí. Wọ́n má ń ṣe ọdún Ìbílẹ̀, àti ètùtù ṣíṣe ní ààyè yìí tẹ́lẹ̀.[3][4][5]

  • Akojọ ti awọn isun omi
  • Ikogosi Warm Springs

Àwọn ìwé Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Falodun, Kemi (2017-06-19). "What You Need to Know About Olumirin Waterfall". PropertyPro Insider. Retrieved 2021-07-02. 
  2. "Erin-Ijesha Waterfalls". https://www.vanguardngr.com/2015/04/olumirin-waterfalls-natures-gift-to-erin-ijesha/. 
  3. Uguru, Okorie (2015-02-26). "The Nation - Olumirin Waterfall Splash of the sublime". thenationonlineng.net. Archived from the original on 2015-02-26. Retrieved 2021-07-02. 
  4. "REPORTER’S DIARY: Inside the decrepit Erin-Ijesha Waterfall in Osun". Premium Times Nigeria. 2021-05-16. Retrieved 2021-07-02. 
  5. "Erin-Ijesha Waterfalls is a sanctuary of purity and beauty". https://www.pulse.ng/lifestyle/food-travel/erin-ijesha-waterfalls-a-sanctuary-of-purity-and-beauty/z7j13k2.