Feyisetan Fayose

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Feyisetan Fayose
Ọjọ́ìbíOṣù Kínní 8, 1964 (1964-01-08) (ọmọ ọdún 60)
Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Olùgbèjà-fún-ẹ̀tọ́-àwọn-ẹ̀dá-ènìyàn
Olólùfẹ́Ayo Fayose

Feyisetan Fayose jẹ́ onínúure-tí-ń-ta-ọ̀pọ̀-ènìyàn-lọ́órẹ, ọmọ bíbí ilẹ̀ Nàìjíríà, tí ó tún jẹ́ olùgbèjà fún ẹ̀tọ́ àwọn ẹ̀dá ènìyàn, àti pé obìnrin-àkọ́kó ti ìlú Ekiti State nígbà kan rí ni, gẹ́gẹ́ bí i aya Ayọ̀ Fáyọ́ṣe.[1][2][3]

Wọ́n bí Feyisetan Fayose ní ọjó kẹ̀jọ, osù kínní, ọdún 1964. Feyisetan jẹ́ ọ̀gá pátátá apá ẹgbẹ́ àwọn obìnrin onísẹ́-ìròyìn ti ìlú Èkìtì lápapọ̀.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ekiti First Lady warns against indiscriminate sex". Pulse Ng. Retrieved December 20, 2016. 
  2. "Wife of Gov. Fayose speaks on sex". News Agency of Nigeria. Archived from the original on December 13, 2016. Retrieved December 20, 2016. 
  3. "FEYISETAN: The soothsayer, succour provider in Ekiti Govt House". Retrieved December 20, 2016. 
  4. "Feyisetan Fayose Becomes NAWOJ Partroness". Ekiti State Government. Archived from the original on February 4, 2017. Retrieved December 20, 2016.