Franca Brown

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Franca Brown
Ọjọ́ìbíFranca Obianuju Brown
17 Oṣù Kàrún 1967 (1967-05-17) (ọmọ ọdún 56)
Onitsha, Anambra state
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaAhmadu Bello University and University of Jos
Iṣẹ́Actress

Franca Obianuju Brown (bíi ni ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù karùn-ún, ọdún 1967), jẹ́ òṣèré lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó gbà àmì ẹ̀yẹ City People Movie Special Recognition Award láti ọ̀dọ̀ City People Entertainment Awards ní ọdún 2016.[1][2]

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Brown bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ St Mary's Primary School ní ìlú Onitshaìpínlẹ̀ Anambra. Ó gboyè nínú ìmò òfin láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Ahmadu Bello University. Ó tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Jos níbi tí ó tí gboyè nínú ìmò eré orí ìtàgé.[3]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Brown gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré fún ipá tí ó kó nínú eré Behind The Clouds.[4][5] Kí ó tó kópa nínú eré náà, ó má ń ṣe eré orí ìtàgé rán pé. Ó kópa nínú eré rán pé tí àkọ̀rí rẹ̀ jẹ́ Swam Karagbe. Brown jẹ́ adarí fún eré, òun sì ni ó dárí eré Women at Large.

Ní ọdún 2019, ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ dáná sun ilé rẹ̀[6][7][8]

Àmì Ẹ̀yẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2016, ó gbà àmì ẹ̀yẹ City People Movie Special Recognition Award láti ọ̀dọ̀ City People Entertainment Awards.[9][10]

Àwọn Ìtọ́kàsi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. People, City (2019-10-22). "Gists From The 2019 City People Movie Awards – Read About The Movie Stars That Rocked". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-12. 
  2. Magazine, Yes International! (2017-03-22). "WHY I’M STILL SINGLE – Veteran Actress, Franca Brown". Yes International! Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-12-12. Retrieved 2019-12-12. 
  3. Alao, Biodun (2019-02-12). "How I Have Maintained My Sexy Shape At Over 50 - Actress Franca Brown". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-12. 
  4. Alao, Biodun (2019-02-12). "How I Have Maintained My Sexy Shape At Over 50 - Actress Franca Brown". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-12. 
  5. "Why I have not married — Franca Brown". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-06-05. Retrieved 2019-12-12. 
  6. Haliwud (2016-02-10). "Possessed Housemaid Burns Down The Home Of Nollywood Actress, Franca Brown". Information Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-12. 
  7. "Franca Brown House-help burns down actress’ house". www.pulse.ng. Retrieved 2019-12-12. 
  8. Odunayo, Adams (2016-02-08). "So sad! Maid sets veteran Nollywood actress' house on fire". www.legit.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-12. 
  9. People, City (2019-10-22). "Gists From The 2019 City People Movie Awards – Read About The Movie Stars That Rocked". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-12. 
  10. Ogunseye, Zainab (2016-07-27). "Nigerian, Ghanaian celebrities storm awards event in eye popping dresses (photos)". www.legit.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-12.