Godman Akinlabi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Godman Akinlabi
Ọjọ́ìbíGodman Akinlabi
28 Oṣù Kejìlá 1974 (1974-12-28) (ọmọ ọdún 49)
Oyo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Pastor
Ìgbà iṣẹ́2010–present

Godman Akinlabi (tí wọ́n bí ní 28 December 1974) jẹ́ olùṣọ́-àgùntàn ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó sì tún jé òǹkọ̀wé, asọ̀rọ̀-ní-gbangba, àti onímọ̀-ẹ̀rọ. Òun ni olùdarí ìjọ The Elevation Church.[1]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Godman Akinlabi ní December 28, 1974. Ìlú Igbo-Ora, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ló ti wá, ìyẹn ní apá Ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Ìlú Ìbàdàn ló dàgbà sí, ó sì lọ sí ilé-ìwé Government College, Ibadan, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, níorílẹ́-èdè Nàìjíríà láti ọdún 1985 wọ 1990. Ní ọdún 1992, wọ́n gbà á sí Federal University of Technology Akure, ní Ìpínlẹ̀ Òndó láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa Mining àti Mineral Engineering, ní èyí tó sì gboyè èkọ́ Bachelor of Technology (B.Tech.) ní ọdún 1997. Ó gboyè ẹ̀kó ti master's degree ní international diplomacy ní University of Lagos. Ó jé akẹ́kọ̀ọ́ gboyè láti Manchester Business School, England, níbi tó ti gboyè MBA.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Chika Ebuzor (3 January 2017). "The Clergy - Focus on Pastor Godman Akinlabi" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Pulse Nigeria. 
  2. "Meet Pastor Godman" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-04-07.