Isaac Boro Park

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Isaac Boro Park jẹ́ pápá ìṣeré kan tí ó wà ní agbègbè Old GRA ní Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Rivers, Port Harcourt.[1] Wọ́n so pápá ìṣeré náà lórúkọ tẹ́lé Isaac Boro, ẹni tí ó jẹ́ ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2] Ibi tí ó wà ní pàtó ni: 4°47'16"N (4.787960), 7°0'19"E (7.005517).[3]

Ó wà ní odi kejì Mile One, ó sì jẹ́ ilé fún erẹ́ baseball àti softball ní Port Harcourt.[4] Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà láti ọdún 2006 sí ọdún 2013, wọn ṣe ayẹyẹ international trade fair Ọdọọdún níbẹ̀, ó sì tún jẹ́ ibi tí wọ́n ti ń ṣe ayẹyẹ ìrántí ikú àwọn ọmọ ológun tí ó sọ èmí wọn nù lójú ogun, fún Ọjọ́ àwọn Òṣìṣẹ́ àti ayẹyẹ ìparí àwọn Kópà National Youth Service.[5][6][7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Naku, Dennis (2014-05-08). "Bring Back Our Girls’ protest hits Rivers". Nationalmirroronline.net. Archived from the original on 15 July 2014. Retrieved 2014-06-08.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Akasike, Chukwudi (2014-02-09). "Isaac Boro Park: Fading glory of a historical centre". Punchng.com. Archived from the original on 7 June 2014. Retrieved 2014-06-08.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Isaac Boro Park (Port Harcourt)". Wikimapia.org. Retrieved 2014-06-08. 
  4. "Baseball Chief Hails Rivers League". Nationalnetworkonline.com (Port Harcourt, Nigeria: Network Printing and Publishing Company). 2013-10-30. Archived from the original on 2014-07-27. https://web.archive.org/web/20140727002725/http://www.nationalnetworkonline.com/vol10n43/sports.html. 
  5. Alli, Franklin (2006-12-14). "Port Harcourt Now Trade Fair Hub As 278 Firms Participate". The Nigeria Business.com. Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2014-06-08. 
  6. Izejiobi, Kingsley (2013-11-18). "Trade fair begins in Port Harcourt". Treasure 98.5 FM. Retrieved 2014-06-08. 
  7. "RSG Releases Armed Forces Remembrance Day Programme". The Tide (Port Harcourt, Nigeria: Rivers State Newspaper Corporation). 2012-01-06. http://www.thetidenewsonline.com/2012/01/06/rsg-releases-armed-forces-remembrance-day-programme/.