Jeremiah Omoto Fufeyin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jeremiah Omoto Fufeyin
Ọjọ́ìbí15 February 1971
Burutu, Delta State, Nigeria
Iṣẹ́Televangelist minister, philanthropist
Ìgbà iṣẹ́2010 - present
OrganizationChrist MercyLand Deliverance Ministry (CMDM)
Olólùfẹ́Anthonia Fufeyin
Àwọn ọmọ5
Websitechristmercyland.org

Jeremiah Omoto Fufeyin (tí wọ́n bí ní 15 February 1971, sí Burutu, ní Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà) jẹ́ olùdásílẹ̀ àti wòlíì àgbà ti ìjọ Christ Mercyland Deliverance Ministry (CMDM), Effurun, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, Nàìjíríà.[1] Ó ṣe ìdásílẹ̀ ìjọ náà ní 3 April 2010.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ẹbí rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Jeremiah Omoto Fufeyin sí ìlú Burutu, ní Warri, ìpínlẹ̀ Delta, Nàìjíríà ní 15 February 1971.[2] Ó ṣe ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní Zuokumor Primary School ní Burutu L.G.A ti ìpínlẹ̀ Delta láàrin ọdún 1981 sí 1986.[3] Ó lọ sí ilé-ìwé girama rẹ̀ ní Gbesa Grammar School Ojobo, láàrin ọdún 1986 sí 1992.[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Prophet Fufeyin urges wealthy pastors to assist less-privileged". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-19. Retrieved 2022-03-15. 
  2. Fufeyin, Jeremiah (31 May 2015). "I am not Junior TB Joshua —Fufeyin of MercyLand - Vanguard News". http://www.vanguardngr.com/2015/05/i-am-not-junior-tb-joshua-fufeyin-of-mercyland/. 
  3. "Prophet Series:Nigeria's globally recognized prophets (1)". Openlife (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-21. Retrieved 2020-05-30. 
  4. daylight Nigeria, Prophet Jeremiah: Liberating souls, changing lives, through power of God, 3 September 2016