Kemi Omololu-Olunloyo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kemi Omololu-Olunloyo
Ọjọ́ìbí6 Oṣù Kẹjọ 1964 (1964-08-06) (ọmọ ọdún 59)
Ibadan, Oyo State, Nigeria
Iṣẹ́Journalist, blogger, activist
Parent(s)Victor Omololu Olunloyo

Kemi Omololu-Olunloyo (Olukemi Omololu-Olunloyo, tí a bí ní ọjọ́ kẹfà, osù kẹjọ,1964) jè akọ̀ròyìn, ajàfẹ́tọ̀ọ́ọmọnìyàn, àti gbajúmọ̀ lórí ìkànnì ayélujára ní Nàìjíríà. Ó jẹ́ gbajúmọ̀ ní orí ìkànnì ayélujára ní Nàìjírìà, pàápàá jùlọ, fún síse àríyànjiyàn lóri àwọn ọ̀rọ̀ tí ó múni lókàn, bi ìfẹ̀ónú hàn ti END SARS ní ọdún 2020 àti ikú akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ àdáni kan ní Èkó. Omololu-Olunloyo ti dojúkọ àfisùn orísii nípa ayé àti isẹ́ rẹ̀; tí púpọ̀ rẹ̀ ò sì jẹ́ òtítọ́.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Hundeyin, David (16 December 2021). "How to Spoof an Entire Career: The Curious Story of Kemi Olunloyo: A middle-aged Nigerian woman was deported from Canada in 2012. What happened next illustrates how far tall tales and sheer audacity can take one in Africa's largest country". West Africa Weekly. Retrieved 16 December 2021.