Mallam Dendo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Mallam Muhammadu Bangana tí a tún mọ̀ sí Mallam Dendo tàbí Manko, jẹ́ olókìkí tó gbajúmọ̀ nínú ìtàn ní ọ̀rúndún kọkàndínlógún ní ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ Fulani lati ibi ti a mọ̀ sí ìpínlẹ̀

Keb ní òde onibi, ti o wa ni Ariwa Naijiria . [1]


Ni ọrundun kànkàndínlógún, nígbàtí agbègbè Sudan n ṣe àwọn àyípadà pàtàkì nítorí àwọn ìṣẹgun tí Uthman dan Fodio ṣe, Mallam Dendo lọ sí orílè-èdè Nupe. Àkókò yìí jẹ́ àmì ìgbà tí àwọn ènìyàn Nupe tẹríba fún Emir ti Gwandu .

Mallam Dendo dára gáan ni òṣèlú àti ètò lápapò. A mọ fún ṣíṣe nkán tuntun ní Nupe,

A rántí Mallam Dendo fún ìfẹ láti ka ẹkọ Islam àti jíjẹ olórí tó dangajia. Ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀, láti kíkọ ẹ̀kó nípa Islam àti Olùdarí, fihàn bí o ṣe ní ipá lórí itan-akọọlẹ Nupe.

Pàápàá lóni, àwọn ènìyàn sì n ronú nípa àwọn ohun ti Mallam Dendo tí ṣe. O jẹ èyán pàtàkì ní itan-akọọlẹ Nupe ati ìwúrí fún awọn mìíràn láti ronú àti kọ ẹ̀kọ́. [2]

  1. Mallam Dendo 
  2. Olubiyo (2003-01-01). The Nupe People of Nigeria. https://www.academia.edu/520030/The_Nupe_People_of_Nigeria.