Oha soup

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ọbẹ̀ Oha
Ọbẹ̀ Oha
Alternative namesOha soup
Place of originNàìjíríà
 

Ọbẹ̀ Oha jẹ́ ọbẹ̀ tó wọ́pọ̀ ní apá gúúsù mọ́ ìlà-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà .[1][2][3]

Ọbẹ̀ oha jẹ́ ọbẹ̀ agbègbè Ìlà-oòrùn, tó sì jẹ́ pé àwọn ará Íbò ni wọ́n sábà máa ń sè é, láti ará igi ewébẹ̀ láéláé tí orúkọ sáyẹ́ńsì rẹ̀ ń ṣe Pterocarpus mildraedii ni ọbẹ̀ náà ti ṣẹ̀.[4]

Èròjà tó ṣe pàtàkì jùlọ fún ọbẹ̀ náà ni ewébẹ̀ oha, àwọn mìíràn tún ni úsísá, áṣí( amọ́bẹ̀ kí), ẹran, edé, epo pupa àti iyọ̀. Àwọn orúkọ mìíràn tí wọ́n tún ń pe ọbẹ̀ náà ni uha àti ọbẹ̀ ora.[5][6]

Àwọn Oúnjẹ tí ẹ le fi jẹ Oha[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọbẹ̀ oha/Uha dára jù lọ pẹ̀lú fùfú. Iyán, sẹ̀mó, ọlá àti ẹ̀bà gbogbo àwọn wọ̀nyí náà ni wọ́n dára pẹ̀lú ọbẹ̀ oha.[7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Travel, Jumia (February 2, 2021). "Tasty Foods From Eastern Nigeria". ModernGhana. 
  2. Ejiofor, Yvonne (October 11, 2017). "HOW TO MAKE OHA SOUP". The Guardian. 
  3. BN TV (June 30, 2021). "Sisi Yemmie's Step by Step Oha Soup Recipe & Preparation". BellaNaija. 
  4. "Top Five Tasty Nigerian Soups For Tourists". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-08-04. Retrieved 2022-06-27. 
  5. "Ofada rice, unripe plantain, Oha soup, other African food that aid weight loss". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-27. Retrieved 2022-06-27. 
  6. Adebimpe, Alafe (2020-03-18). "Spices and Recipes: How to prepare the delicious Oha soup [Video Tutorial]". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-27. 
  7. "Steps To Making Oha Soup". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-12. Retrieved 2022-06-27.