Osita Osadebe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chief Stephen Osita Osadebe
Fáìlì:Chief Osadebe.jpg
Background information
Orúkọ àbísọStephen Osita Osadebe
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiOsadebe, The Doctor of Hypertension
Ọjọ́ìbí(1936-03-17)17 Oṣù Kẹta 1936
Atani, Colony of Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Atani, Nigeria
Aláìsí11 May 2007(2007-05-11) (ọmọ ọdún 71)
St. Mary's Hospital Waterbury, Connecticut, United States
Irú orinIgbo Highlife
Occupation(s)singer, songwriter, record producer
Years active1958–2007
LabelsPolygram Records Nigeria
Associated actsThe Empire Rhythm Orchestra, Prince Nico Mbarga, Rex Lawson, Celestine Ukwu, Eddie Okonta, Victor Olaiya, Fred Coker, Victor Uwaifo
WebsiteChief Osita at Calabash music

Chief Stephen Osita Osadebe /θj/(tí wọ́n bí ní March 17, 1936[1] tó sì ṣaláìsí ní May 11, 2007),[2] tí ọ̀pọ̀ ènìuàn mọ̀ sí Osita Osadebe, jẹ́ olórin, tó wá láti Atani. Ọ̀kan lára àwọn orin rẹ̀ tó gbajúgbajà tó kọ ní ọdún 1984 tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Osondi Owendi", èyí tó fi ẹsẹ̀ rẹ̀ múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn orin oeílẹ̀-èdè yìí tó gbajúmọ̀ jù lọ.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àdàkọ:Cite AV media notes
  2. "Chief Stephen Osita Osadebe Passes Away On May 11, 2007". Global Rhythm Magazine News. May 15, 2007. Archived from the original on January 29, 2013. Retrieved April 5, 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Nigeria's Chief Stephen Osita Osadebe dead". United Press International. May 19, 2007. Retrieved 2010-04-05.