Oye Owolewa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Oye Owolewa
Shadow Member of the
U.S. House of Representatives
from the District of Columbia's
at-large district
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
January 3, 2021
AsíwájúFranklin Garcia
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1989 (ọmọ ọdún 34–35)
Nigeria[1]
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic
EducationNortheastern University (BS, PharmD)
WebsiteCampaign website

Adeoye "Oye" Owolewa (tí wọ́n bí ní ọdún 1989)[2][3] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ olóṣèlú, olóògùn, àti ọmọ-ẹgbẹ́ Democratic Party. Ní oṣù November, ọdún 2020, wọ́n yàn án sípò ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ti orílẹ̀-èdè America.[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named niara
  2. Olowolagba, Fikayo (November 5, 2020). "US Election: Oye Owolewa Made Nigeria Proud". Daily Post. Archived from the original on November 13, 2020. Retrieved November 15, 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Adeoyo Owolewa Twitter". Retrieved November 9, 2020. 
  4. "General Election 2020 - Election Night Unofficial Results". District of Columbia Board of Elections. November 3, 2020. Archived from the original on November 4, 2020. Retrieved November 4, 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)