Saheed Aderinto

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Saheed Aderinto
Ọjọ́ìbí(1979-01-22)Oṣù Kínní 22, 1979
Ibadan, Oyo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian, American
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ibadan, University of Texas, Austin
Iṣẹ́professor, historian, writer
EmployerFlorida International University
Gbajúmọ̀ fúnHistorical scholarship
Notable workAnimality and Colonial Subjecthood: The Human and Nonhuman Creatures of Nigeria; Guns and Society in Colonial Nigeria
Olólùfẹ́Olamide Aderinto
Àwọn ọmọItandola • Itandayo
Awards2023 Dan David Prize; Nigerian Studies Association Book Prize for "When Sex Threatened the State."
Websitesaheedaderinto.com

Saheed Aderinto (tí wọ́n bí ní January 22, 1979) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó ń kọ́ History and African and African Diaspora Studies ni Florida International University. Bákan náà ló jẹ́ òǹkọ̀wé tó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmi-ẹ̀yẹ. Òun ni olùṣẹ̀dásílẹ̀ Lagos Studies Association.[1] NÍ oṣù February, ọdún 2023, Aderinto gba ẹ̀bùn $300,000, èyí tó jẹ́ ti Dan David Prize.[2][3] Ó ti ṣàtẹ̀jáde ìwé mẹ́jọ, jọ́nà mẹ́rìndínlógójì, átíkú ogójì àti ìríwísí sí ìwé ogún.[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Aderinto leads establishment of Lagos Studies Association – WCU News" (in en-US). WCU News. April 13, 2017. https://news-prod.wcu.edu/2017/04/aderinto-leads-establishment-lagos-studies-association/. 
  2. "Dan David Prize". Dan David Prize (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-28. 
  3. "Dan David Prize, World’s largest history prize announces 2023 winner" (in en-US). The Jerusalem Post | JPost.com. https://www.jpost.com/israel-news/article-732970. 
  4. "Curriculum Vita – Saheed Aderinto". faculty.wcu.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-04-11. Retrieved 2018-02-03.