Samuel Akínsànyà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Samuel Adétáyọ̀ Akínsànyà
Ọjọ́ìbíkìíní oṣù kẹjọ ọdún 1898
Ishara, Nàìjíríà
AláìsíJanuary 1985
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Odemo (or traditional king) of Isara and political activist
Gbajúmọ̀ fúnPolitical activism and King of Isara
Akisanya in his younger days
Odemo Akisanya celebrating his birthday

Samuel Akínsànyàtí Wọ́n bí lọ́jọ́ kìíní oṣù kẹjọ ọdún 1898, tí ó sìn kú lọ́dún 1985 (1 August 1898 – 1985)[1] jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ òṣìṣẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó gbé ní ìlú Èkó nígbà ayé àwọn òyìnbó amúnisìn, ó jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ àwọn ọ̀dọ́ tí wọ́n pè ní Nigerian Youth Movement.[2] Bákan náà, ó jẹ́ ọba aládé ìlú Ìsarà lọ́dún 1941 títí ó fi wàjà. Lónìí, wọ́n gbà pé òun ni ọba tí gbajúmọ̀ jùlọ nínú ìtàn ìlú náà.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. PeoplePill. "About Samuel Akisanya: Nigerian activist (1898 - n/a) - Biography, Facts, Career, Wiki, Life". PeoplePill (in Èdè Ruwanda). Retrieved 2020-10-06. 
  2. Gann, Brian (2011-05-03). "The Nigerian Youth Movement (1934-1951)". BlackPast is dedicated to providing a global audience with reliable and accurate information on the history of African America and of people of African ancestry around the world. We aim to promote greater understanding through this knowledge to generate constructive change in our society. Retrieved 2020-10-06.