Sarah Àdegoke

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sarah Adegoke
Orílẹ̀-èdè Nigeria
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Keje 1997 (1997-07-16) (ọmọ ọdún 26)
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (double–handed backhand)
Ẹnìkan
Iye ìdíje1–8 (WTA)
Ẹniméjì
Iye ìdíje1–10 (WTA)
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 874
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 884(2019)
Last updated on: 06 March 2019.

Sarah Adegoke ni elere tennis lobinrin ni orilẹ ede Naigiria ti a bini ọdun 1997 ti o si dagba si ibadan nibi ti o sì kọ tennis lati ọwọ baba rẹ, Ọgbẹni Adegoke Adedapọ. Arabirinin naa ni ẹni ti a rank ju ninu elere tennis lobinrin ni orilẹ ede Naigiria[1].

Aṣeyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ni ọdun 2012, sarah jẹ àkọkọ runnerup lori idije Tennis CBN[2]
  • Ni ọdun 2014, sarah ni obinrin ti a rank jù ni tennis órilẹ ede Naigiria[3]
  • Ni óṣu february 2017, sarah pegede ninu Idije Club Master Tennis ni ilu Ikoyi[4]

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.celebsagewiki.com/sarah-adegoke
  2. https://twmagazine.net/news/events/meet-sarah-adegoke-the-first-lady-of-tennis/
  3. https://dailytrust.com/amp/nigerian-tennis-stars-say-year-2014-is-eventful
  4. https://guardian.ng/sport/imeh-adegoke-are-rainoilikoyi-club-masters-tennis-champions/