Selim Aga

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Selim Aga (c. 1826 – tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 1875) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Sudan kan tí àwọn olókowò ẹrú Arab jígbé nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́jọ, tí wọ́n sì mú wá sí Scotland ní ọdún 1836, níbi tí wọ́n ti tọ dàgbà gẹ́gẹ́ bi ọkùnrin llómìnira. Selim kọ ìwé nípa ayé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ẹrú, ó sì sọ nípa Ode to Britain ní ọdún 1846.[1] Ó ma ọ̀pọ̀ ní Great Britain nípa Áfíríkà, ó sì tẹ̀lé William Balfour Baikie ní 1857 láti lọ Niger River. Lẹ́yìn náà, ó tẹ̀lé John Hawley Glover àti Richard Francis Burton nínú ìrìn àjò wọn káàkiri Áfíríkà. Ní àwọn ọdún 1860s, Selim lọ sí Liberia,[2] àwọn jàndùkú Grebo pá ní ọdún 1875.

Ìgbà èwe rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Selim Aga, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe sọ nípa ara rẹ̀, sínú pẹ̀tẹ́lẹ̀ Taqali.[3] Àwọn ènìyàn Taqali ń ṣíṣẹ́ àgbẹ̀ àti olùṣọ́ àgùntàn, ẹ̀sìn wọn ni Islam àti sísin Oòrùn. Àwọn akónilẹ́rú jí Selim gbé nígbà tí ó ń da nǹkan ọ̀sìn bàbá rẹ̀. Ó sìn lábé olówó mẹ́wàá, ẹni kẹwàá ni Robert Thurburn (Mr. R. T.), British consul in Alexandria.[4][5] Robert kọ́ Selim ní èdè Ínglísì, wọ́n sì mu lọ Cataracts of the Nile.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Selim Aga
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named M6
  3. Selim Aga, p. 14
  4. Selim Aga, p. 34
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named M1