Tọpó Àgbádárìgì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìlú Tọpó jẹ́ ìlú kán tí ó wà ní eré-kùṣù agbègbè ìlú Àgbádárìgììpínlẹ̀ Èkó, bákan náà ni Ìlú Tọpó jẹ́ ibi tí àwọn ajíyìn rere Kátólíìkì kọ́kọ́ gbin àgbọn sí ní ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 1845,[1] ibẹ̀ náà sì ni wọ́n kọ́kọ́ dá ilé ẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ sí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2]


Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Topo populated place, Nigeria". Nigeria. Retrieved 2018-12-11. 
  2. "Make Topo-Badagry coconut plantation tourists site - Monarch". The Eagle Online. 2018-09-01. Retrieved 2018-12-11.