Taiwo Abioye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Taiwo Abioye
Ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmò Englisi ní Covenant University
In office
2013–2016
Ígbákejì adarí at Covenant University
In office
2012–2016
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kínní 1958 (1958-01-17) (ọmọ ọdún 66)
Ipinle Kaduna
ResidenceCanaanland, Ipinle Ogun
Alma materAhmadu Bello University
(Bachelor of Education in Language Arts)
Ahmadu Bello University
( Master of Arts in English)
Ahmadu Bello University
(Doctor of Philosophy in English)

Taiwo Olubunmi Abioye jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Englisi ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti di Ìgbàkejì adarí Covenant University.[1]

Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Taiwo ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù kínní ọdun 1958, ní Kaduna sínú ìdílé àwọn òbí tó wá láti Ìpínlẹ̀ Ogun, Abioye gba àmì-ẹ̀yẹ àkọ́kọ́ nínú ìmò Language Arts Yunifásítì Àmọ́dù Béllò. Bákan náà ẹ̀wẹ̀, ó tẹ̀síwájú láti gba àmì-ẹ̀yẹ Master àti ti Dókítá ní ilé-ìwé kan náà ní ọdun 1992 àti 2004.[2] Ní ọdun 1982, Abioye gba àmì-ẹ̀yẹ akẹ́kọ̀ọ́ tó mọ̀wé jùlọ ni ẹ̀ka Inglisi ti Yunifásitì Àmọ́dù Béllò.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Oyedepo urges FG to Increase funding to education". World Stage. January 18, 2018. Archived from the original on 2018-01-30. Retrieved 2018-01-30. 
  2. admin (2017-11-22). "Taiwo Abioye" (PDF). covenantuniversity.edu.ng. Retrieved 2017-11-22. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. admin. "Prof Taiwo Olubunmi Abioye". covenantuniversity.edu.ng. Archived from the original on 2017-09-24. Retrieved 2017-11-23.