Uju Okeke

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Uju Okeke
Ọjọ́ìbíObianuju Blessing Okeke
Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaNnamdi Azikiwe University
Iṣẹ́Nollywood Actress
Ìgbà iṣẹ́2004–present
Olólùfẹ́Melekh

Obianuju Blessing Okeke tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi Uju Okeke jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ó kó nínú eré Mission to Nowhere àti The Barrister. Wọ́n bíi Obianuju sí ìpínlè Anambra. Ó gboyè nínú ìmò eré orí ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Yunifásítì Nnamdi Azikiwe.[1] Ní ọdún 2012, ó fẹ́ Melekh, wọ́n sí ṣe ìgbéyàwó wọn ní ilé ìjọsìn ti Saint Barth Anglican Church ní ìpínlẹ̀ Èkó.[2]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2006, Okeke kó ipa ọmọ ọ̀dọ̀ nínú eré Mission to Nowhere èyí tí Teco Benson gbé kalẹ̀. Ní ọdún 2017, ó gbà àmì ẹ̀yẹ Next Upcoming Artist láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Academy Awards fún ipa tí ó kó nínú eré náà.[3]

Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó
2006 The Barrister Actress
2006 Mission to No Where Actress: Maid

Àwọn Ìtọ́kàsi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Honour for Uju Okeke from her alma mater". The Guardian. Retrieved 12 October 2020. 
  2. "Nollywood actress Uju Okeke ties the knot". thenigerianvoice. Retrieved 12 October 2020. 
  3. "Honour for Uju Okeke from her alma mater". The Guardian. Retrieved 12 October 2020.