William Rashidi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
William Rashidi
Ọjọ́ìbíWilliam Rashidi
Orílẹ̀-èdèỌmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Iṣẹ́Human Rights Activist, and HIV Activist
Gbajúmọ̀ fúnHuman Rights Activism, LGBTIQ Advocacy, and Social Justice
TitleHuman Rights Activist

William Rashidi jẹ́ ajìjàngbara fún àwọn ọmọ egbẹ́ LGBTQ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ń lọ́wọ́ nínú ìbálòpọ̀ láàrin akọ sí akọ àti abo sí abo. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ ìgbìmọ̀ tí ó ń darí ilé ṣiṣi fún ìlera àti àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn. Òun tún ni Olùdarí ti Equality Triangle Initiative, èyí tí ó fìdíkalẹ̀ sí Ipinle Delta, orílè-èdè Nàìjíríà.[1][2] Ó tún jẹ́ alágbàwí fún lilo Prophylaxis Pre-ifihan, (PReP) láti lè fi dènà ìkọlù àrùn HIV.[3] Ní ọdún 2011, ó ṣe ìlòdì sí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlá fún ìgbéyàwó láàrin ọkùnrin sí okùnrin àti obìnrin sí obìnrin èyí tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé aṣòfin àgbà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ di òfin. [4]

Ẹ̀kọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

William Rashidi kọ́ ẹ̀kọ́ gboyè jáde ni public policy láti ilé-èkó gíga Yunifásítì ti Queen Mary tí ó wà ní ìlú Londonu.

Àwọn Àtẹ̀jáde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • A syndemic of psychosocial health problems is associated with increased HIV sexual risk among Nigerian gay, bisexual, and other men who have sex with men (GBMSM).

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "William Rashidi". AVAC. 2018-02-05. Retrieved 2021-09-14. 
  2. "Williams Rashidi – Channels Television". Channels Television – The Latest News from Nigeria and Around the World. Retrieved 2021-09-14. 
  3. "NGO Calls For Investment In New HIV Prevention, Treatment – The Whistler Nigeria". The Whistler Nigeria – Exclusive Stories, Breaking News, Government, Politics, Business. Retrieved 2021-09-14. 
  4. "Nigerian gay man on country's hostility" (in en-GB). https://www.bbc.com/news/av/world-africa-16006716.