Yoruba People in the Atlantic slave trade

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn ènìyàn Yorùbá ṣe kó ipa púpọ̀ nínú àṣà àti ètò ọrọ̀-ajé nínú òwò ẹrú ti òwo ẹrú Atilantiki láti ìgbà tí a lè sọ pé ó ti wà ní ọdún 1400 títí di 1900 CE.[1][2][3]

Ẹḿpáyà Ọ̀yọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Láti ọdún 1400 lọ, ni aláyélúà ti Ẹḿpáyà Ọ̀yọ́ ti kógo sí sọ èdè Yorùbá di lingua franca sí gbogbo àwọn agbègbè Volta.[4][5] Ní bí ìparí 18th century, wọ́n pa àwọn ọmọ ogun Ọ̀yọ́ tì nítorí kò sí ìdí kan púpọ̀ láti ṣẹ́gun.[6][7] Bíi bẹ́ẹ̀, Ọ̀yọ́ kọjú gbogbo akitiyan wọn sórí òwò àti jíjẹ́ alárenà fún àwọn olówò ẹrú trans-Saharan àti trans-Atlantic.[6] Àwọn European gbé iyọ̀ wọ òde Ọ̀yọ́ lásìkò ìjọba Ọba Obalokun.[8] Ká dúpẹ́ fún jíjẹ gàba rẹ̀ ní ìdó náà, jẹ́ kí àwọn olókoòwò Ọ̀yọ́ lè ṣòwò pọ̀ pẹ̀lú àwọn European ní Porto Novo àti Whydah.[9] Níbí yìí ni wọ́n ti ta àwọn ẹrú àti àwọn ọ̀daràn Ọ̀yọ́ Ẹḿpáyà fún àwọn òǹrà Dutch àti Portuguese.[10][11]

Ipa Àṣà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní àfikún sí ipa tí òwò ẹrú kó, àti lẹ́yìn(ò-rẹyìn oúnjẹ àti èdè àwọn Afro-Amẹríkà, àmúwọlé àṣà Yoruba jẹ́ ẹ̀rí tó nípọn nínú irú àkọọ́lẹ̀ ẹ̀sìn Yoruba bíi Santería, Candomblé Ketu, àti àwọn ẹ̀mí àbáláyé mìíràn.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Pedro Funari; Charles E. Orser Jr. (2014). Current Perspectives on the Archaeology of African Slavery in Latin America (SpringerBriefs in Archaeology). Springer. p. 138. ISBN 978-1-493-9126-43. https://books.google.com/books?id=2f9MBQAAQBAJ&pg=PA108. 
  2. Toyin Falola; Ann Genova (2005). Yoruba Creativity: Fiction, Language, Life and Songs. Africa World Press. p. 134. ISBN 978-1-592-2133-68. https://books.google.com/books?id=TJ3vI7ryh8cC&pg=PA134. 
  3. Olatunji Ojo (2008). "The Organization of the Atlantic Slave Trade in Yorubaland, ca.1777 to ca.1856". The International Journal of African Historical Studies (The International Journal of African Historical Studies (Boston University African Studies Center)) 41 (1): 77–100. JSTOR 40282457. 
  4. Stride àti Ifeka 1971, p. 302.
  5. Stride, George; Ifeka, Caroline (1971) (in English). Peoples and Empires of West Africa West Africa in History, 1000–1800. New York: Africana Pub. Corp.. ISBN 9780841900691. OCLC 600422166. https://books.google.com/books?id=3_VyAAAAMAAJ. 
  6. 6.0 6.1 Oliver àti Atmore 2001, p. 95.
  7. Oliver, Roland; Atmore, Anthony (2001-08-16) (in en). Medieval Africa, 1250–1800. Cambridge University Press. ISBN 978-0-521-79372-8. https://books.google.com/books?id=4o-OZ5w-BmMC. 
  8. Stride àti Ifeka p. 292
  9. Stride &àti Ifeka 1971, p. 293.
  10. Smith 1989, p. 31.
  11. Clarence-Smith, Gervase, ed (1989) (in en). The Economics of the Indian Ocean Slave Trade in the Nineteenth Century. London: Psychology Press. ISBN 978-0-7146-3359-6. https://books.google.com/books?id=9Hfl5rpXM1sC&pg=PP11. 

Àdàkọ:African diaspora Àdàkọ:Yoruba topics