Àádùn
Ìrísí
Àádùn jẹ́ oúnjẹ ipanu ìgboro tí o gbajúmọ̀ láàrin àwọn ìpínlẹ̀ Yoruba ní Nàìjíríà. Orúkọ àádùn túmọ sí adùn àti pé o tún máa n ṣẹ iranṣẹ ní ibi igbeyawo àti àwọn ayẹyẹ isọsọ. [1]
Akopọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn èròjà mẹ́rin tí o wọpọ tí a lo fún ṣíṣe àádùn ní iyẹfun àgbàdo, ata chilli, èpo ọpẹ àti ìyọ́. Oríṣi ipanu méjì lo wà tí wọn sì jẹ: iyẹfun àgbàdo tí kò dára àti èyí tí o jẹ́ tí èpo ọpẹ́. Awọn ará òkun láti ipinle kogi tún fi ẹwà tí wọn ti yọ sínú iyẹfun àgbàdo wọn kì wọn tó fi ewé ògèdè ṣẹ láti fún ní itọwo otooto.
Wo eleyii na
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Nigerian onjewiwa