Àìsàn ikú òjijì ọmọdé (SIDS)
Àdàkọ:Use American English Àdàkọ:Infobox medical condition (new) Sudden infant death syndrome (SIDS) tí ó túmọ̀ sí àrùn Àìsàn ikú òjijì ọmọdé jẹ́ àrùn abàmì tí ó máa ń jásí ikú òjijì ọmọdé tí ọjọ́-orí kò ju ọdún kan lọ. Àwọn ikú òjijì báyìí ni a kì í mọ ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó fà wọ́n, kódà, bí àwọn onímọ̀ bá ṣe àyẹ̀wò ohun tí ó fà ìṣẹ̀lẹ̀ ikú òjijì náà.[1] Àìsàn ikú òjijì ọmọdé, SIDS sáàbà máa ń ṣẹlẹ̀ láti ojú orun.[2] Typically death occurs between the hours of midnight and 9:00 a.m.[3] Kìí sáàbà máa ń sí ariwo tàbí ẹ̀rí ìjaporó.[4] Àìsàn ikú òjijì ọmọdé, SIDS jẹ́ àrùn kan tí ó máa ń pa àwọn ọmọdé julọ àwọn orílẹ̀ èdè ńlá àgbáyé, ó kó ìdáméjì nínú ikú tí ó ń pa àwọn ọmọdé.[5]
The exact cause of SIDS is unknown.[6] Wọ́n tí ṣàlàyé àwọn nǹkan tí ó máa ń ṣokùnfà àrùn ikú òjijì ọmọdé, lára àwọn nǹkan náà ni àwọn àsìkò tí àrùn lè wora fún ènìyàn, àwọn àsìkò idagbasoke kan, àti àwọn nǹkan tí ó wà ní àyíká àgbègbè wa.[2][6] Àwọn ìnira àgbègbè bẹ́ẹ̀ lè jẹ́ súnsùn sórí ikùn tàbí ẹgbẹ́, oru púpò lápọ̀jù, àti gbígbóòórùn sìgá.[6] ìfúnrapọ̀ lórí ibùsùn tàbí ìjàmbá nípa pínpín ibùsùn lò máa ń fà á.[2][7] Nǹkan mìíràn tí ó máa ń fà á ní bíbí ọmọ láìtò ọjọ́. Bí àpẹẹrẹ, bíbí ọmọ ṣáájú oṣù kẹsàn-án.[8] SIDS makes up about 80% of sudden and unexpected infant deaths (SUIDs).[2] Àwọn ìdá ogún tó kù tí ó máa ń fa àrùn ikú òjijì sáàbà máa ń jẹ́ àrùn àrànmọ́, àìṣedede ara òbí, àti àrùn ọkàn.[2] Nígbà mìíràn ẹ̀wẹ̀, ṣíṣe àbùkù ọmọdé nípa híhá wọn gogo ni àṣìṣe àyẹ̀wò máa ń tọ́ka sí pé ó fà á, èyí kò sí rí bẹ́ẹ̀ rárá, èyí ni wọ́n gbà pé ó máa ń fa ìdá márùn-ún àrùn ikú òjijì ọmọdé.[2]
Ọ̀nà kan tí ó dára jù lọ láti dẹkùn àrùn ikú òjijì ọmọdé ni rírí i dájú pé a tẹ́ ọmọdé tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò tó ọdún kan láti sùn kàkà.[8] Awon ọ̀nà mìíràn tún ni ibùsùn tìmùtìmù tó rọ̀ díẹ̀, tí ó sì jìnnà díẹ̀ sí olùtọ́jú ọmọ, tí ó gbọ́dọ̀ lápá tí kọ́ni fi jẹ́ kí ọmọ wo ṣubú, ní ibùgbé tó dára fún orun, èyí tí ọmọdé kò ní fi gbọ́ oòrùn sìgá.[9] Breastfeeding and immunization may also be preventive.[9][10] Lára àwọn ọ̀nà àbáyọ tí kò wúlò ni, àwọn nǹkan láti tẹ́ ọmọ sípò ibùsùn kan, àti baby monitors.[9][10] Evidence is not sufficient for the use of fans.[9] Ìbákẹ́dùn àwọn ìdílé tí ọfọ̀ àrùn ikú òjijì ṣẹ̀ pàtàkì, nítorí gbogbo wa là mọ̀ pé ikú òjijì ọmọdé kò dára rárá, tí kìí sáàbà máa ń ní ẹlẹ́rìí, síbẹ̀, tí ìwádìí sì máa ń wáyé.[2]
Bí àrùn ikú òjijì ṣe máa ń pọ̀ tó máa ń yàtọ̀ ni ìlọ́po mẹ́wàá ni àwọn orílẹ̀ èdè tí wọ́n ti dàgbà sókè láti ókan nínú ẹgbẹ̀rún kan sí ókan nínú ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá.[2][11] Káàkiri àgbáyé, àrùn ikú òjijì máa ń fà ikú ọmọdé tí ó tó 19,200 ọdún 2015, ó sì fa ikú ọmọdé tó tó 22,000 ọdún 1990.[12] Àrùn ikú òjijì, SIDS jẹ́ àrùn kẹta tí ó burú jù lọ tí ó ń pa àwọn ọmọdé tí ọjọ́ orí wọn kéré sí ọdún kan lórílẹ̀ èdè Amerika lọ́dún 2011.[13] Ó jẹ́ àrùn tí ó ń pa ọmọdé julọ, pàápàá ọmọdé tí ọjọ́ orí rẹ̀ jẹ́ oṣù kan sí ọdún kan.[8] Ó tó ìdá àádọ́rùn-ún, (90%) àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ikú òjijì ọmọdé ló máa ń ṣẹlẹ̀ kí irú àwọn ọmọ bẹ́ẹ̀ tó tọ́ oṣù mẹ́fà, ó sáàbà máa ń ṣẹlẹ̀ sí ọmọ oṣù méjì sí mẹ́rin.[2][8] It is more common in boys than girls.[8] Iye tí ikú òjijì ọmọdé ti dín kù ní ìdá ọgọ́rin sí i ní àwọn agbègbè tí idanilekoo oòrùn àlàáfíà sísùn fún àwọn ọmọdé bá wà.[11]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Centers for Disease Control and Prevention, Sudden Infant Death". Archived from the original on March 18, 2013. Retrieved March 13, 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 2.5 2.6 2.7 2.8 "The sudden infant death syndrome". The New England Journal of Medicine 361 (8): 795–805. August 2009. doi:10.1056/NEJMra0803836. PMC 3268262. PMID 19692691. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3268262.
- ↑ Optiz, Enid Gilbert-Barness, Diane E. Spicer, Thora S. Steffensen; foreword by John M. (2013). Handbook of pediatric autopsy pathology (Second ed.). New York, NY: Springer New York. pp. 654. ISBN 9781461467113. https://books.google.com/books?id=yaPjAAAAQBAJ&pg=PA654. Retrieved 15 September 2017.
- ↑ Sethuraman, C; Coombs, R; Cohen, MC (2014). "Sudden Unexpected Death in Infancy". In Cohen, MC. Pediatric & Perinatal Autopsy Manual. Cambridge. pp. 319. ISBN 9781107646070. https://books.google.com/books?id=t33sAwAAQBAJ&pg=PA319.
- ↑ Raven, Leanne (2018), Duncan, Jhodie R.; Byard, Roger W., eds., "Sudden Infant Death Syndrome: History", SIDS Sudden Infant and Early Childhood Death: The Past, the Present and the Future, Adelaide (AU): University of Adelaide Press, ISBN 978-1-925261-67-7, PMID 30035955 Check
|pmid=
value (help), archived from the original on 27 July 2022, retrieved 2020-09-28 Unknown parameter|url-status=
ignored (help) - ↑ 6.0 6.1 6.2 "What causes SIDS?". National Institute of Child Health and Human Development. 12 April 2013. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 9 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Ways To Reduce the Risk of SIDS and Other Sleep-Related Causes of Infant Death". NICHD. 20 January 2016. Archived from the original on 7 March 2016. Retrieved 2 March 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 8.0 8.1 8.2 8.3 8.4 "How many infants die from SIDS or are at risk for SIDS?". National Institute of Child Health and Human Development. 19 November 2013. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 9 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 9.0 9.1 9.2 9.3 "Sudden infant death syndrome: an update". Pediatrics in Review 33 (7): 314–20. July 2012. doi:10.1542/pir.33-7-314. PMID 22753789.
- ↑ 10.0 10.1 "How can I reduce the risk of SIDS?". National Institute of Child Health and Human Development. 22 August 2014. Archived from the original on 27 February 2015. Retrieved 9 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 11.0 11.1 Duncan, Jhodie R.; Byard, Roger W. (2018), Duncan, Jhodie R.; Byard, Roger W., eds., "Sudden Infant Death Syndrome: An Overview", SIDS Sudden Infant and Early Childhood Death: The Past, the Present and the Future, University of Adelaide Press, ISBN 9781925261677, PMID 30035964 Check
|pmid=
value (help), archived from the original on 2 July 2020, retrieved 2019-08-01 Unknown parameter|url-status=
ignored (help); Unknown parameter|name-list-style=
ignored (help) - ↑ Wang, Haidong et al. (Oct 2016). "Global, regional, and national life expectancy, all-cause mortality, and cause-specific mortality for 249 causes of death, 1980-2015: a systematic analysis for the Global Burden of Disease Study 2015". Lancet 388 (10053): 1459–1544. doi:10.1016/s0140-6736(16)31012-1. PMC 5388903. PMID 27733281. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=5388903.
- ↑ "Deaths: Preliminary data for 2011". National Vital Statistics Reports. 61 (6): 8. 2012. PMID 24984457. https://www.cdc.gov/nchs/data/nvsr/nvsr61/nvsr61_06.pdf.