Àfin Beaumont

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àfin Beaumont ní ọdún 1785

Àfin Beaumont , tí wọ́n Henry I kọ́ sí gúúsù ọ̀nà àbáwọlé Oxford ní ọdún 1130 gẹ́gẹ́ bí àfin ọba kí ó lè súnmọ́ ibi tí ọba ti ń rẹra ní Woodstock (nísìn ó jẹ́ ara Àfin Blenheim).

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]