Àgbàdo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àgbàdo
Illustration showing male and female maize flowers
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Ìjọba: Ọ̀gbìn
Clade: Vascular plant
Clade: Flowering plant
Clade: Monocotyledon
Clade: Commelinids
Ìtò: Poales
Ìdílé: Poaceae
Ìbátan: Zea (plant)
Irú:
Z. mays
Ìfúnlórúkọ méjì
Zea mays
Zea mays "fraise"
Zea mays "Oaxacan Green"
Zea mays "Ottofile giallo Tortonese”

Àgbàdo (Látìnì: Zea mays) ni ó jẹ́ óuńjẹ jij́ẹ oní hóró tí àwọn ènìyàn ilẹ̀ apá Gúúsù ilẹ̀ Mexico ṣe àwárí rẹ̀ ní ǹkan bíi egberun mewa odun seýin. ọkà kan tí wọ́n kọ́kọ́ jẹ́ sísọ di ohun ọ̀gbìn látọwọ́ àwọn ẹ̀yà abínibí ní apágúúsù Mẹ́ksíkò bíi ọdún 10,000 sẹ́yìn.[1][2][3][4] Igi agbado ma n yo ewe sooro, ti o si ma n yo irukere ti o ni eruku ododo ni owo oke eyi ti o ma n se atona fun yiyo omo agbado[5][6] . Awon nimo sayensi feran lati maa pee ni Maize (agbado) nitori wipe oruko yi o gbajumo julo fun irufe ounje onihoro yi, ti o si ni itumo orisirisi lodo awon eniyan ni orile agbaye.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "The Evolution of Corn". University of Utah HEALTH SCIENCES. Retrieved 2 January 2016. 
  2. Benz, B. F. (2001). "Archaeological evidence of teosinte domestication from Guilá Naquitz, Oaxaca". Proceedings of the National Academy of Sciences 98 (4): 2104–2106. Bibcode 2001PNAS...98.2104B. doi:10.1073/pnas.98.4.2104. PMC 29389. PMID 11172083. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=29389. 
  3. "The Evolution of Corn". University of Utah HEALTH SCIENCES. Retrieved 2 January 2016. 
  4. Benz, B. F. (2001). "Archaeological evidence of teosinte domestication from Guilá Naquitz, Oaxaca". Proceedings of the National Academy of Sciences 98 (4): 2104–2106. Bibcode 2001PNAS...98.2104B. doi:10.1073/pnas.98.4.2104. PMC 29389. PMID 11172083. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=29389. 
  5. "Please settle a dispute. Is sweet corn a vegetable or a grain? What is the difference? How about field corn? - eXtension" (in en). USDA National Institute of Food and Agriculture, New Technologies for Ag Extension project. http://articles.extension.org/pages/36971/please-settle-a-dispute-is-sweet-corn-a-vegetable-or-a-grain-what-is-the-difference-how-about-field-. 
  6. Chodosh, Sara (8 July 2021). "The bizarre botany that makes corn a fruit, a grain, and also (kind of) a vegetable". Popular Science. Retrieved 24 February 2022.