Jump to content

Àgbàjọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
A community of interest gathers at Stonehenge, England, for the summer solstice.

Àgbàjọ'je adipo awon iru eda ti won ni ibasepo ti won pin morawon ayika. Ninu awon agbajo eniyan, ero-okan, igbagbo, alumoni, iferan, ilo, ewu, ati awon ohun miran ni won le wa bi ikanna larin won, to n fa idamo awon olukopa ati bi won o se ni itori larin ara won si.