Àgbègbè Ìwọ̀-ọọ̀rùn, Rwanda

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Etí òkun Muhazi
Agbègbè Eastern

Intara y'Iburasirazuba
CountryRwanda
CapitalRwamagana
Districts
Government
 • GovernorCG Emmanuel K. GASANA (2021-)
Area
 • Province9,458 km2 (3,652 sq mi)
Population
 (2022 census)[2]
 • Province3,563,145
 • Density380/km2 (980/sq mi)
 • Urban
745,935
 • Rural
2,817,210
Other settlementsKibungo, Nyagatare, Nyamata, Gahini, Kabarore, Kagitumba
HDI (2021)0.526 [3]
low · 2nd of 5

Eastern Province (Faransé: Province de l'Est; Duki: Oostelijke Provincie) ni agbègbè tí ó tóbi jù, tí ó sì ní àwọn olùgbé tí ó pọ̀ jù nínú àwọn agbègbè márùn-ún tí ó wà ní Rwanda. Wọ́n da kalẹ̀ ní oṣù kínní ọdún 2006 gẹ́gẹ́ bi ara àwọn ǹkan tí ìjọba Rwanda láti pín agbára kakiri àwọn agbègbè ni Rwanda.

Agbègbè náà pín sí ìletò méje: Bugesera, Gatsibo, Kayonza, Ngoma, Kirehe, Nyagatare àti Rwamagana. Rwamagana ni Olú-ìlú agbègbè náà.

Akagera National Park wà ní agbègbè yí.

Àtòjọ àwọn ìletò ní agbègbè ìlà oòrùn Rwanda nípa iye àwọn olùgbé wọn(2012)[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ipò wọn ní Eastern Province
Districts
,
2012[4]
Ipò wọn ní
Rwanda
Districts
,
2012
Ìletò
Àwọn olùgbé ibẹ̀ ní
15 August 2012
Àwọn olùgbé ibẹ̀ ni
15 August 2002
Ìyàtọ̀ nínú àwọn olùgbé ni
2002 sí 2012

(%)
Population Density
2012

(km2)
Population Density
Rank,
Eastern Province
2012
&0000000000000001.0000001 &0000000000000002.0000002 Nyagatare 466,944 255,104 83.0 243 6
&0000000000000002.0000002 &0000000000000003.0000003 Gatsibo 433,997 283,456 53.1 275 5
&0000000000000003.0000003 &0000000000000009.0000009 Bugesera 363,339 266,775 36.2 282 4
&0000000000000004.0000004 &0000000000000010.00000010 Kayonza 346,751 209,723 65.3 179 7
&0000000000000005.0000005 &0000000000000013.00000013 Ngoma 340,983 235,109 44.0 390 2
&0000000000000006.0000006 &0000000000000015.00000015 Kirehe 338,562 229,468 48.6 288 3
&0000000000000007.0000007 &0000000000000026.00000026 Rwamagana 310,238 220,502 40.7 455 1
Àpapò - Agbegbe ìlà oòrùn 2,660,814 1,700,137 53.0 275 -

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Area Calculation (see below)
  2. Citypopulation.de Population of Eastern Province
  3. "Sub-national HDI - Area Database - Global Data Lab". hdi.globaldatalab.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 8 August 2021. 
  4. "2012 Population and Housing Census (Provisional Results) | National Institute of Statistics Rwanda". Archived from the original on 6 December 2012. Retrieved 2012-12-06.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)