Àgbérò Pythagoras

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
The Pythagorean theorem: The sum of the areas of the two squares on the legs (a and b) equals the area of the square on the hypotenuse (c).

Àgbérò Pythagoras ninu mathematics, je ibasepo ninu Jeometri Euklid larin awon egbe meteta anigunmeta onigunrege. O so pe:

Ninu anigunmeta rege ti iba je, itobi alopomeji ti egbe re je hypotenusi (egbe ti o ko ju si igun rege) dogba mo aropo awon itobi awon alopomeji ti won je ti egbe meji to ku (egbe mejeji ti won pinu si ibi ti igun rege wa).

A le ko agbero yi sile gege bi asedogba:

nibiti c ti duro fun gigun hypotenusi, ti a ati b si duro fun awon gigun awon egbe meji to ku.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]