Àgbọn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Àdàkọ:Speciesbox

Àgbọn jẹ́ èso tí Igi Àgbọn máa ń so. Ó jẹ́ èso tí ó wúlò lọ́pọ̀lọpọ̀, pàápàá jùlọ fún jíjẹ, ìwòsàn ṣíṣe, àdí-àgbọn àti àwon ohun èlò mìíràn tí wọ́n máa ń fi Àgbọn ṣe. [1] [2]

Ìwúlò àgbọn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oríṣiríṣi nǹkan ni Àgbọn wúlò fún. Bí wọ́n ṣe ń jẹ Àgbọn bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ń fi í ṣe oríṣiríṣi nǹkan mìíràn.

Àgbọn wà fún jíjẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ènìyàn lè jẹ funfun inú èso àgbọn tí ó bá gbó kákạ́. Kódà, àwọn mìíràn máa ń jẹ́ funfun inú èso àgbọn tí kò gbó. Ní jíjẹ, a máa ń fi Àgbọn mú gaàrí, wọ́n ń fi Àgbọn se ìrẹsì (coconut rice) àti àwọn oúnjẹ mìíràn. [1]

Àdí Àgbọn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdí Àgbọn jẹ́ epo tí wọ́n máa ń ṣe láti ara funfun inú èso Àgbọn. A lè fi àdí-àgbọn se ọbẹ̀, a lè fi jẹ iṣu, kókò, gbágùúdá sísè àti àwọn oúnjẹ mìíràn. Wọ́n máa ń fi àdí-àgbọn ṣe ọṣẹ àti àwọn ohun èlò mìíràn.[3]

Ìwòsàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìwádìí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fihàn pé ẹgbẹlẹmùkú ìwòsàn ni wọ́n lè fi Àgbọn ṣe. [4] [5]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 "Coconut 101: Nutrition Facts, Health Benefits, Beauty Benefits, Recipes". EverydayHealth.com. 2019-07-12. Retrieved 2020-01-21.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "EverydayHealth.com 2019" defined multiple times with different content
  2. "https://eatingwell.com". EatingWell. Retrieved 2020-01-21.  External link in |title= (help)
  3. Facty (in Èdè Swahili) https://facty.com/food/nutrition/12-benefits-of-coconut-oil/?style=quick&utm_source=adwords&adid=340211024806&utm_medium=m-search&utm_term=&utm_campaign=**FHINT3-search-dynamic-ads&gclid=CjwKCAiA35rxBRAWEiwADqB376RPKTU7EdHdLrgcMOqbDIvbgm_37MxL50qEQkMjtvP1VyxtoMqyJxoCbdEQAvD_BwE. Retrieved 2020-01-21.  Missing or empty |title= (help)
  4. Nutritionist, Jo Lewin - Registered (2019-07-05). "The health benefits of coconut milk". BBC Good Food. Retrieved 2020-01-21. 
  5. Luciano, Mary (2018-10-29). "Healing Wonders Of Coconuts - 10 Benefits Of Coconut [INFOGRAPHIC]". Sunwarrior. Retrieved 2020-01-21.