Jump to content

Àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní Mẹ̀lílà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
COVID-19 pandemic in Melilla
ÀrùnCOVID-19
Irú kòkòrò èrànSARS-CoV-2
IbiMẹ̀lílà
Ìjásílẹ̀ àkọ́kọ́Wuhan, Hubei, China via Spain
Arrival dateọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 2020
(4 years, 8 months, 3 weeks and 1 day)
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn107
Iye àwọn tí ara wọn ti yá27
Iye àwọn aláìsí
2

Wọ́n kọ́kọ́ kéde Ìbẹ́sílẹ̀ Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní Mẹ̀lílà lórílẹ̀ èdè Spain lóṣù kẹta ọdún.

Bí àrùn náà ṣe ń jàkálẹ̀ láti ìgbà dé ìgbà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oṣù kẹta ọdún 2020

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Arákùnrin kan tí ó rìnrìn-àjò láti àgbègbè kan tí wọ́n ń pè ní Iberian Peninsula ló kó àrùn náà wọ Mẹ̀lílà, àgbègbè àwọn ọmọ adúláwò Áfríkà ní orílẹ̀ èdè Spain. [1]

Oṣù kẹrin ọdún 2020

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nígbà tí ó má fi di ọjọ́ kẹrìndínlógùn oṣù kẹrin ọdún 2020, ó ti tó iye ènìyàn mẹ́tàlélọ́gọ́rùn-ún tí wọ́n ti kéde wọn pé wọ́n kó àrùn Covid-19. Wọ́n kéde ẹni mẹ́tàdínlọ́gbọ́n, 27 tí wọ́n wòsàn, tí ẹnì méjì péré sìn kú.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ministerio de Sanidad, Consumo y Bienestar Social - Profesionales - Teléfonos de información - Coronavirus". www.mscbs.gob.es. Archived from the original on 4 April 2020. Retrieved 2020-04-07. 
  2. "Un positivo más en COVID-19 y tres nuevos recuperados en Melilla". El Faro de Melilla (in Èdè Sípáníìṣì). 2020-04-15. Retrieved 2020-04-16.