Àlá
Ìrísí

Àlá jẹ́ ìran tí a rí lójú oorun wa. Àlá a má múnú ẹni fùn tàbí kí ó bani lẹ́rù, fúni ní ìpòrúùru ọkàn, ó le jẹ́ èyí tí ó dùn noni nínú tàbí bani nínú jẹ́. Lópọ̀ ìgbà, ẹni tí ó lálàá a má a jí pẹ̀lú àárẹ̀ ara kí ó sì má le sun padà mọ́ lẹ́yìn tí ó ti jí fúngbà diẹ̀. Bí ènìyàn kò bá le sun mọ́ látàrí àlá burukú, ó lè fa àìsàn sí àgọ́ ara ẹni.
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwòrán àpẹẹrẹ àlá mìíràn
