Àlùbọ́sà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àlùbọ́sà

Àlùbọ́sà jẹ́ irú ohun ọ̀gbìn kan pẹ̀lú orúkọ sáyẹ́nsì Allium cepa (ní èdè Látìnì). Àlùbọ́sà jẹ́ ewébẹ̀ewé àtí kókò rẹ̀, tí a dá wọn mọ́ pẹ̀lú òórùn àti ìtalẹ́nu wọn, ṣe é jẹ bíi oúnjẹ.