Àrá kangúdù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

'Síkírù Adéṣínà tí ó lògbà láàrin ọdún 1971 sí ọjọ́ kẹjọ, oṣù Kejì Ọdún,2016), tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí Àrákangúdù, jẹ́ òṣèré omo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó tún jẹ́ Olùdarí àti olóòtú sinimá. [1] Ó jẹ́ gbajúgbajà nípa kí kópa gégé bí Oníṣègùn, Ọlọ́ṣà tàbí ògbóǹtarìgì Aláwo nínú àwọn fíìmù tí ó ti kópa.[2]Ní ọjọ kẹjọ, oṣù Kejì Ọdún Ẹgbàá-lé-mẹ́ẹ̀dógún ni ọ ṣàìsí ní ilé rẹ ní Kaduna, apá ìha àríwá Nàìjíríà.[3][4]

Àwọn fíìmù tí ó ti kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Tèmi Ni, Tì ẹ Kọ́
 • Ìdùnú Mi
 • Ìlù Gángan
 • Ògbólògbó
 • Ìyà Ojú Ogun
 • Èrè Àgbèrè
 • Àgbẹ̀dẹ Ògún
 • Àgbà Òṣùgbó
 • Ajé Olókun
 • Ìyá Ọkọ Bournvita
 • Ìgbà Òwúrọ̀
 • Ayaba Òòṣà
 • Àjànà orò
 • Fìjàbí
 • Ojú Ọ̀daràn Ré

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]