Àròkọ Oníròyin
Ìrísí
Àròkọ Oníròyìn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àròkọ Oníròyìn jẹ́ àròkọ tí a fi ń ròyìn ìṣẹ̀lẹ̀ kan tí ó sojú ẹni tàbí èyí tí wọ́n sọ fún ni, Ṣé Yorùbá bọ̀ wọ́n ni ohun tó ṣojú ẹni kì í sẹ̀yìn ẹni bẹ́ẹ̀ ni ìròyìn kò tó àfojúba, ẹni tí ó dé ibẹ̀ ló lè sọ.
Àpẹẹrẹ Àròkọ Oníròyìn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ọdún iléyá tí ó wáyé ní ọdún yìí
- Bí mo ṣe lo ìsinmi mi tí ó kọjá
- Ọjà alẹ́ ní ìlú mi
Ètò lẹrù igi, ó ṣe pàtàkì nígbà tí a bá ń kọ àròkọ oníròyìn, a gbọ́dọ̀ ròyìn nǹkan náà tàbí ṣe àpejúwe ohun tí à ń ròyìn ní ọ̀nà tí ó jẹ́ pé ẹni tí kò rí ohun nǹkan náà yóò fi fi ojú ya àwòrán ohun tí à n sọ nípa rẹ̀
A kò gbọ̀dọ̀ ṣe àfikún tàbí àyọ̀kù ìṣẹ̀lẹ̀ tí a n ṣe ìròyìn
rẹ̀ .[1]