Jump to content

Àrùn ọkàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àrùn okàn jé ọrò gbogbògbò tí a lò láti ṣe àpèjuwe èyíkéyi nínú àrùn tí o kan ọkàn àti/tàbí àwọn ohun èlò èjè, wọn pẹlu orisirisi iru àrùn bi ìkùnà okàn àti aìsàn okàn míràn

Àrùn ọkàn jé okunfa ikú fun awọn ọkunrin, awọn obinrin, ati eniyan awọn òpòlopò èyà ni Ilu Amẹrika.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]