Obìnrin
Obìnrin ènìyàn je abo eniyan tiosi je iyọ̀ ayé. Obìnrin je òun elege. Ó jé èèyàn dáadáa to má ń ṣe atileyin fún ọmọ àti ọkọ
Kò sí obìnrin tí kò rẹwà tí ó bá rí ìfẹ́ àti itoju ẹwà rẹ yóò jáde bí ti òdodo yóò sì má wù ni jọjọ.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |