Jump to content

Àsìá ilẹ̀ Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Federal Republic of Nigeria
UseNational flag Fáìlì:FIAV Equal.svg Fáìlì:FIAV Vertical unknown.svg
Proportion1:2
AdoptedOṣù Kẹ̀wá 1, 1960; ọdún 63 sẹ́yìn (1960-10-01)
DesignA vertical bicolour triband of green, white and green.
Designed byMichael Taiwo Akinkunmi
Variant flag of Federal Republic of Nigeria
UseState flag
Proportion1:2
DesignA vertical bicolour triband of a green, white and green; charged with the coat of arms in the centre.
Variant flag of Federal Republic of Nigeria
UseCivil ensign Fáìlì:FIAV Mirror.svg
Proportion1:2
DesignA red field with the national flag, in the canton
Variant flag of Federal Republic of Nigeria
UseState ensign
Proportion1:2
DesignA blue field with the national flag, in the canton
Variant flag of Federal Republic of Nigeria
UseNaval ensign Fáìlì:FIAV Mirror.svg
Proportion1:2
DesignA white field with the national flag in the canton, with the Naval seal in the fly.
Variant flag of Federal Republic of Nigeria
UseAir force ensign Fáìlì:FIAV Mirror.svg
Proportion1:2
DesignA sky-blue field with the national flag in the canton, with the air force roundel in the fly.

Àsíá ilẹ̀ NàìjíríàMichael Taiwo Akinkunmi ṣe ní wọ́n gbà wọlé gẹ́gẹ́ bí i èyí tó máa ṣojú Nàìjíríà láti òru ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1960, ọjọ́ tí Nàìjíríà gba òmìnira. Wọ́n fi ọ̀rọ̀ àsíá yìí ṣe ìdíje, tí àwọn ènìyàn ẹgbẹ̀rún mẹ́tà sì dá sí. Àsíá tí Akinkunmi ṣe ni wọ́n gba wọlé láàárín àwọn èyí tí gbogbo àwọn tó kópa nínú ìdíje náà ṣe. Àwọ̀ àsíá náà jẹ́ aláwọ̀ ewé-funfun-aláwọ̀ ewé, tí aláwọ̀-ewé náà dúró fún iṣẹ́-àgbè, tí funfun sì dúró fún àlàáfíà àti ìṣọ̀kan.Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]