Àtòjọ Àwọn Oǹkọ̀wé-bìnrin ọmọ China

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn wọ̀nyí ni Àtòjọ Àwọn Oǹkọ̀wé-bìnrin ọmọ China.

B[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Consort Ban (c. 48 – c. 6 BCE) ọ̀mọ̀wé àti Akéwì
 • Ban Zhao (45 – c. 116) historian
 • Bao Junhui (fl. late 8th c. CE) Akéwì
 • Bao Linghui (fl. c. 464 CE) Akéwì
 • Anni Baobei (born 1974) oǹkọ̀wẹ́ ìtàn
 • Bing Xin (1900–1999) oǹkọ̀wẹ́ ìtàn méèrirí àti ìwé ọmọdé.

C[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

D[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oǹkọ̀wé ìtàn àròsọ

F[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

G[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

H[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

J[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

K[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Ke Yan (1929–2011) akọ̀wé eré-oníṣe, oǹkọ̀tàn àti Akéwì

L[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Li Qingzhao (1084 – c. 1151) Oǹkọ̀wé àti Akéwì
 • Li Ye (ó kú ní 784) Akéwì
 • Liang Desheng (1771–1847) Akéwì àti Oǹkọ̀wé
 • Lin Huiyin (1904–1955) asọ̀tàn ohun-àlùmọ́nì
 • Lin Zongsu (1878–1944) akàròkọ nípa ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin
 • Ling Shuhua (1900–1990) akọ̀wé ìtàn ìgbàlódé àti oníṣẹ́ ọ̀nà
 • Liu Rushi (1618–1664) Akéwì
 • Liu Ying (born 1974) oǹkọ̀tàn
 • Lü Bicheng (1883–1943) Akéwì àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀
 • Luo Luo (born 1982) oǹkọ̀tàn
 • Lüqiu Luwei (born 1969) oníròyìn

M[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Mian Mian (born 1970) Oǹkọ̀wé ìtàn àròsọ

P[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Lynn Pan (born 1945) Oǹkọ̀wé ìrìn-àjò

Q[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Qiu Jin (1875–1907) Akéwì, akàròkọ àti Oǹkọ̀wé nípa òṣèlú

R[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Rao Xueman (wọn bí ní 1972) oǹkọ̀tàn àròsọ, aláròkọ àti oníròyìn òfegè
 • Ru Zhijuan (1925–1998) aláròkọ

S[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

T[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Tian Yuan (born 1985) akọrin, akọ̀wé àti Oǹkọ̀wé
 • Tie Ning (born 1957) oǹkọ̀tàn àti oǹkọ̀tàn wẹ́wẹ́

W[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Wang Qinghui (1264–1288) Akéwì
 • Wang Anyi (wọ́n bi lọ́dún 1954) fiction writer
 • Wang Wei (1597–1647) Akéwì
 • Wang Xufeng (wón bí lọ́dún 1955) Oǹkọ̀wé nípa ohun mímu, tíì àti oǹkọ̀tàn
 • Wang Yun (1749–1819) Akéwì àti akọ̀wé eré-oníṣe
 • Yun Wang (wọ́n bi ní ọdún 1964) Akéwì
 • Woeser (wọ́n bí ní lọ́dún 1966) blogger, poet and essayist
 • Wu Chuntao (wọ́n bi lọ́dún 1963) Oǹkọ̀wé nípa àwùjọ
 • Wu Zao (1799–1862) Akéwì

X[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Xi Xi (wọ́n bi lọ́dún 1938) Oǹkọ̀wé àti Akéwì
 • Xia Jia (wọ́n bi lọ́dún 1984) Oǹkọ̀wé àròsọ nípa sáyẹ́ǹsì àti ìtàn méèrií
 • Xiao Hong (1911–1942) oǹkọ̀tàn ati aláròkọ
 • Xie Bingying (1906–2000) oǹkọ̀tàn nípa àwọn ènìyàn
 • Xie Daoyun Akéwì àti ọ̀mọ̀wé
 • Empress Xu (Ming dynasty) (1362–1407)
 • Lady Xu Mu (fl. 7th c. BCE) poet
 • Xu Hui (627–650) Akéwì
 • Xu Kun (born 1965) postmodern fiction writer
 • Xu Zihua (1873–1935) Akéwì
 • Xue Susu (c. 1564 – c. 1650) Akéwì
 • Xue Tao (768–831) Akéwì
 • Xinran (born 1958) akọ̀tàn

Y[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Yang Erche Namu (wọ́n bí lọ́dún 1966) Oǹkọ̀wé nípa àwùjọ
 • Yang Gang (1905–1957) oníròyìn, oǹkọ̀tàn àti aṣògbufọ̀
 • Yang Hongying (wọ́n bi lọ́dún 1962) children's fiction writer
 • Yang Jiang (1911–2016) akọ̀wé eré-oníṣe, oǹkọ̀tàn àti aṣògbufọ̀
 • Ting-Xing Ye (wọ́n bi lọ́dún 1952) author of young adult novels
 • Ye Yingchun (born 1970) commentator
 • Chia-ying Yeh (born 1924) Akéwì ati ọ̀mọ̀wé
 • Yu Xuanji (c. 840 – c. 868) Akéwì.

Z[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]