Jump to content

Àtòjọ àwọn ọdún tí wọ́n ṣe lórílẹ́-èdè Tunisia

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Onírúurú ayẹyẹ ni wọ́n máa ń ṣe ní orílẹ̀-èdè Tunisia lọ́dọọdún, èyí tí a pín wọ́n pẹ̀lú oṣù tí wọ́n máa ń ṣe wọ́n nínú àtòjọ ìsàlẹ̀ yìí...

Àtòjọ àwọn ọdún tí wọ́n ń ṣe ní Tunisia pẹ̀lú oṣù wọn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Ọdún ohun èlò ìkọrin làgbàáyé. Tí ó ń sọ nípa àwọn àṣà àwọn tí wọ́n ń bẹ ní àríwá ilẹ̀ ÁfíríkàTunis
  • Ọdún ìrékọjá – El-Ghriba Synagogue, Djerba. (oṣù kẹrin tàbí oṣù karùn-ún)
  • Ọdún Jerid – Nefta àti káàkiri gbogbo àyíká ìlú
  • Ọdún orin . Orin àlùjó àti tàkasúfèé – Sfax
  • Ọdún Chouftouhonne - Tunis
  • Ọdún yíya àwòrán lábẹ́ omi Coralis – Tabarka
  • Ọdún wáìnì – Grombalia
  • Odunwíìtì – Béja

Oṣù kẹwàá sí oṣù Kejìlá

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Ọdún fíìmù ti Carthage (Journées cinématographiques de Carthage, JCC) - Tunis
  • Ọdún ìkórè Date – Kebili (oṣù kọkànlá)
  • Ọdún Oases káríayé – Tozeur (Oṣù Kọkànlá)
  • Ọdún káríayé ti Sahara. Ijó, orin, àti eré orí ìtàgé - Douz (November–December)
  • Sfax International Mediterranean Film Festival - Sfax (oṣù Kejìlá)

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Carthage Music Festival" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 20 February 2016.