Àwòdì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòdì apẹja (Pandion haliaetus)
Milvus milvus

Àwòdì

Òwe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • A kì í fini joyè àwòdì ká má lè gbádìẹ.
  • A kì í du orí olórí kí àwòdì gbé tẹni læ.
  • Ìlérí adìẹ, asán ni lójú àwòdì.
  • Iṣu àtẹnumọ́ kì í jóná; ọ̀kà àtẹnumọ́ kì í mẹrẹ; àwòdì kì í gbé adìẹ à-tẹnu-kunkun-mọ́.

Pẹ̀lú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]