Àwọn èdè Altaic

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Altaic
Ìpínká
ìyaoríilẹ̀:
East, North, Central, and West Asia and Eastern Europe
Ìyàsọ́tọ̀: Altaic
Àwọn ìpín-abẹ́:
Korean (generally included)[1]
Japonic (generally included)[1]
ISO 639-2 and 639-5: tut
[[File:Altaic family2.svg|350px]]

Awon ede Altaic Àkójopò èdè tí ó tó ogóta tí nnkan bíi mílíònù márùn-dínlógófà ènìyàn ń so ni a ń pè ní ‘Altaic’. Wón ń so àwon èdè wònyí ní Penisula Balkan (Balkan Penisula) ní ìlà-oòrùn àríwá ilè Asia. Wón pín àwon èdè wònyí sí egbé Turkic, Mongolian àti Manchus-Tungus. Àkosílè lórí ìbèrè ìdàgbàsókè àwon èdè yìí kò pò. Àkosílè lórí Turkic wà ní nnkan bíi séńtúrì kéjo (8th Century) sùgbón a kò mo nnkan kan nípa Mongolian sáájú séńtúrì ketàlá (13th Century). Ó tó séńtúrì ketàdúnlógún (17th Century) kí a tó rí àkosílè kanka nípa Manchu. Ní séńtúrì ogún (20th Century), ìgbìyànjú tó ga wáyé láti so àwon èdè yìí di èdè òde òní. Òpòlopò ìwé tí ó wuyì ni ó ń jáde tí a fi àwon èdè àdúgbò ko, bí àpeere, Uzbek. Wón tún se àtúnse sí àwon àkosílè tí ó ti wà télè, bí àpeere TurkishItokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Stratification in the peopling of China: how far does the linguistic evidence match genetics and archaeology? In; Sanchez-Mazas, Blench, Ross, Lin & Pejros eds. Human migrations in continental East Asia and Taiwan: genetic, linguistic and archaeological evidence. 2008. Taylor & Francis.